Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Mark 12:30, »And thou shalt love the Lord thy God...«

3 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Mark 12:30, »And thou shalt love the Lord thy God...«

  1. Fẹ́ràn Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo àyà rẹ àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo agbára rẹ.

  2. Jesu dáhùn pé, “ ‘Fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ, gbogbo ẹ̀mí rẹ àti gbogbo inú rẹ.’

  3. Kí ìwọ kí ó fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo ẹ̀mí rẹ, àti gbogbo agbára rẹ fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ, èyí ní òfin kìn-ín-ní.’