Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Mark 9:44, »Where the worm dieth not...«
Àwọn ẹsẹ nípa Mark 9:44, »Where the worm dieth not...«
“Wọn yóò sì jáde lọ wọn yóò sì lọ wo òkú àwọn tí wọ́n dìtẹ̀ sí mi; kòkòrò wọn kì yóò kú, bẹ́ẹ̀ ni iná wọn ni a kì yóò pa, bẹ́ẹ̀ ni wọn yóò sì jẹ́ ohun ìríra fún gbogbo ọmọ ènìyàn.”
Where their worm dieth not, and the fire is not quenched.