Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: 2 Peter 2:22, »The dog is turned to his own vomit again.«
Àwọn ẹsẹ nípa 2 Peter 2:22, »The dog is turned to his own vomit again.«
Bí ajá ti í padà sí èébì rẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni aṣiwèrè tún ń hu ìwà òmùgọ̀ rẹ̀.
Òwe òtítọ́ náà ṣẹ sí wọn lára, “Ajá tún padà sí èébì ara rẹ̀; àti ẹlẹ́dẹ̀ tí a ti wẹ̀mọ́ tún padà ń yíràá nínú ẹrọ̀fọ̀.”