Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Romans 15:3, »The reproaches of them that reproached...«
Àwọn ẹsẹ nípa Romans 15:3, »The reproaches of them that reproached...«
nítorí ìtara ilé rẹ jẹ mí run, àti ẹ̀gàn àwọn tí ń gàn ọ́ ṣubú lù mí.
Nítorí Kristi pàápàá kò ṣe ohun tí ó wu ara rẹ̀, ṣùgbọ́n bí a ti kọ ọ́ pé, “Ẹ̀gàn àwọn ẹni tí ń gàn ọ́ ṣubú lù mi.”