Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Hebrews 1:6, »And let all the angels of God worship him.«
Àwọn ẹsẹ nípa Hebrews 1:6, »And let all the angels of God worship him.«
Gbogbo àwọn tí ń sin ère fínfín ni ojú yóò tì, àwọn tí ń fi ère gbéraga, ẹ máa sìn ín, gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run!
Àti pẹ̀lú, nígbà tí Ọlọ́run rán àkọ́bí rẹ̀ wá si ayé wa yìí. Ó pàṣẹ pé, “Ẹ jẹ́ kí gbogbo àwọn angẹli Ọlọ́run foríbalẹ̀ fún un.”