Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Mark 12:29, »Hear, O Israel; the Lord our God...«
Àwọn ẹsẹ nípa Mark 12:29, »Hear, O Israel; the Lord our God...«
Gbọ́ ìwọ Israẹli, Olúwa Ọlọ́run wa, Olúwa kan ni.
Jesu dá ọkùnrin yìí lóhùn pé, “Èyí tó ṣe pàtàkì jùlọ nínú àwọn òfin ni èyí tí ó kà báyìí pé, ‘Gbọ́ Israẹli; Olúwa Ọlọ́run wa Olúwa kan ni.