Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Ephesians 4:26, »Be ye angry, and sin not.«
Àwọn ẹsẹ nípa Ephesians 4:26, »Be ye angry, and sin not.«
Ẹ bínú ẹ má ṣe ṣẹ̀, nígbà tí ẹ bá wà lórí ibùsùn yín, ẹ bá ọkàn yín sọ̀rọ̀, kí ó sì dákẹ́ jẹ́.
Nínú ìbínú yín, ẹ máa ṣe ṣẹ̀, ẹ má ṣe jẹ́ kí oòrùn wọ̀ bá ìbínú yín,