Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Látìnú Gbogbo Bíbélì
YCB
21,292
nínú 31,102
Ìṣètò Ìkọ̀wé
Ìtóbi Ìkọ̀wé 100%
Ìrísí lẹ́tà
Ààlà ẹsẹ
Ó kan ẹsẹ rẹ tó ń bọ̀
I.
Nínú àyíká ọ̀rọ̀
Ìpín 5,439 · Orí 1,189
Abala Yìí
Esekiẹli 33:10-20
10 “Ọmọ ènìyàn; sọ fún ilé Israẹli, ‘Èyí yìí ní ìwọ sọ: “Àwọn ìrékọjá àti ẹ̀ṣẹ̀ wa tẹ orí wa ba, àwa sì ń ṣòfò dànù nítorí wọn. Bá wó wa ni a ṣe lè yè?” ’
+ 10 more verses · Esekiẹli 33:10-20
Orí Yìí
Esekiẹli 33
1 Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá:
2 “Ọmọ ènìyàn sọ̀rọ̀ sí àwọn ènìyàn ilẹ̀ rẹ kí ó sì sọ fún wọn: ‘Nígbà tí mo bá fi idà kọlu ilẹ̀ kan, tí àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà yan ọ̀kan lára àwọn ọkùnrin wọn láti jẹ́ alóre wọn,
3 tí ó sì rí i pé idà ń bọ̀ lórí ilẹ̀ náà, tí ó sì fọn ìpè láti kìlọ̀ fún àwọn ènìyàn,
+ 30 more · Esekiẹli 33
Tẹ̀síwájú nínú kíkà
Ìtẹ̀síwájú Àkójọ Mẹ́wàá rẹ
Tẹ̀síwájú nínú kíkà
III.
Túnú ká
Irinṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ 4
Lẹ́yìn gbogbo ẹsẹ lórí ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù yìí, àwọn irinṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ọ̀fẹ́ wà — Strong's, àwọn ìtọkasí ẹsẹ, àlàyé Matthew Henry, àwọn ìwé ìrònú, àti ìkẹ́kọ̀ọ́ jinlẹ̀ lórí àwọn kókó-ọ̀rọ̀.
IV.
Mú un dání
áàpù àti àfikún
Browser Extension
Ìwé Mímọ́ ní Ìka Ọwọ́ Rẹ
Àwọn ẹsẹ Bíbélì lẹ́sẹsẹ, àwọn ayùnfẹ́, ìtàn, àti ìfọkànsìn ojoojúmọ́ — ní tààràtà nínú ọpọ́n irinṣẹ́ aṣàwárí rẹ. Lọ́fẹ̀ẹ́ àti ní ìkọ̀kọ̀.
Fi Sínú Ẹ̀rọ Lọ́fẹ̀ẹ́
Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I: Browser Extension
Gba Ohun Èlò Náà
Fi Sínú Ẹ̀rọ Rẹ
Ó yára, ó sì wà lójú ìbòrí fóònù rẹ — kò nílò ilé ìtajà ìfilọ́lẹ̀. Fọwọ́ kàn án lẹ́ẹ̀kan fún Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ojoojúmọ́.
Gba Ìfilọ́lẹ̀ náà
Bí a ṣe ń fi sílẹ̀: Gba Ohun Èlò Náà
Ọ̀nà Grant Horner
Dán Ètò Àkójọ Mẹ́wàá wò
Ka orí mẹ́wàá lójoojúmọ́ láti inú àkójọ mẹ́wàá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, kí Ìwé Mímọ́ lè túmọ̀ Ìwé Mímọ́. Ètò náà jẹ́ tirẹ̀ — olùtọpa náà jẹ́ tiwa, ọ̀fẹ́ àti láìsí àkáǹtì.
Bẹ̀rẹ̀
Kẹ́kọ̀ọ́ sí i: Ọ̀nà Grant Horner