Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Romans 10:13, »For whosoever shall call upon the name...«
Àwọn ẹsẹ nípa Romans 10:13, »For whosoever shall call upon the name...«
Yóò sí ṣe, ẹnikẹ́ni tí ó ba ké pè orúkọ Olúwa ní a ó gbàlà, nítorí ní òkè Sioni àti ní Jerusalẹmu ní ìgbàlà yóò gbé wà, bí Olúwa ti wí, àti nínú àwọn ìyókù tí Olúwa yóò pè.
“Ẹnikẹ́ni tí ó bá sá à ti pe orúkọ Olúwa ni a ó gbàlà.”