Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Revelation 2:27, »He shall rule them with a rod of iron...«
Àwọn ẹsẹ nípa Revelation 2:27, »He shall rule them with a rod of iron...«
Ìwọ yóò fi ọ̀pá irin ṣe àkóso wọn ìwọ yóò sì rún wọn wómúwómú bí ìkòkò amọ̀.”
‘Òun ó sì máa fi ọ̀pá irin ṣe àkóso wọn; gẹ́gẹ́ bí a ti ń fọ́ ohun èlò amọ̀kòkò ni a ó fọ́ wọn túútúú,’ gẹ́gẹ́ bí èmi pẹ̀lú tí gbà àṣẹ láti ọ̀dọ̀ Baba mi.