Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: John 6:31, »He gave them bread from heaven to eat.«
Àwọn ẹsẹ nípa John 6:31, »He gave them bread from heaven to eat.«
Ó rọ manna fún àwọn ènìyàn láti jẹ, ó fún wọn ní ọkà láti ọ̀run.
Àwọn baba wa jẹ manna ní aginjù; gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé, ‘Ó fi oúnjẹ láti ọ̀run wá fún wọn jẹ.’ ”