Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Galatians 4:30, »Cast out the bondwoman and her son...«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Galatians 4:30, »Cast out the bondwoman and her son...«

  1. ó sì wí fún Abrahamu pé, “Lé ẹrúbìnrin yìí àti ọmọ rẹ̀ jáde, nítorí ọmọ ẹrú yìí kò ní bá ọmọ mi Isaaki pín ogún.”

  2. Ṣùgbọ́n ìwé mímọ́ ha ti wí, “Lé ẹrúbìnrin yìí àti ọmọ rẹ̀ jáde, nítorí ọmọ ẹrúbìnrin kì yóò bá ọmọ òmìnira obìnrin jogún pọ̀.”