Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Romans 10:20, »I was found of them that sought me not...«

3 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Romans 10:20, »I was found of them that sought me not...«

  1. Gbogbo ọjọ́ ni mo ti nawọ́ mi síta sí àwọn ènìyàn ọlọ́rùn líle, tí wọn ń rìn lọ́nà tí kò dára, tí wọ́n sì gbára lé èrò ara wọn

  2. Ṣùgbọ́n Isaiah tilẹ̀ láyà, ó wí pé, “Àwọn tí kò wá mi rí mi; Àwọn tí kò béèrè mi ni a fi mí hàn fún.”

  3. Ṣùgbọ́n nípa ti Israẹli ni ó wí pé, “Ní gbogbo ọjọ́ ni mo na ọwọ́ mi sí àwọn aláìgbọ́ràn àti aláríwísí ènìyàn.”