Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Romans 8:36, »For thy sake we are killed all the day long...«
Àwọn ẹsẹ nípa Romans 8:36, »For thy sake we are killed all the day long...«
Síbẹ̀, nítorí rẹ̀ àwa da àyà kọ ikú, ní ojoojúmọ́ a ń kà wá sí bí àgùntàn fún pípa.
Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé: “Nítorí rẹ̀ ni a ṣe ń pa wá kú ní gbogbo ọjọ́; À ń kà wá sí bí àgùntàn fún pípa.”