Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Matthew 7:23, »Depart from me, ye that work iniquity.«
Àwọn ẹsẹ nípa Matthew 7:23, »Depart from me, ye that work iniquity.«
Kúrò lọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣe iṣẹ́ ibi, nítorí Olúwa ti gbọ́ igbe mi.
Nígbà náà ni èmi yóò wí fún wọn pé, ‘Èmi kò mọ̀ yín rí, ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi ẹ̀yin oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.’