Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: John 19:36, »A bone of him shall not be broken.«

3 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa John 19:36, »A bone of him shall not be broken.«

  1. “Nínú ilé ni ẹ ti gbọdọ̀ jẹ ẹ́; ẹ kò gbọdọ̀ mú èyíkéyìí nínú ẹran náà jáde kúrò nínú ilé. Ẹ má ṣe ṣẹ́ ọ̀kankan nínú egungun rẹ̀.

  2. Ó pa gbogbo egungun wọn mọ́; kò sí ọ̀kan tí ó dá nínú wọn.

  3. Nǹkan wọ̀nyí ṣe, kí ìwé mímọ́ ba à lè ṣẹ, tí ó wí pé, “A kì yóò fọ́ egungun rẹ̀.”