Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: 2 Timothy 2:19, »The Lord knoweth them that are his.«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2 Timothy 2:19, »The Lord knoweth them that are his.«

  1. Ó sì sọ fún Kora àti gbogbo ẹgbẹ́ rẹ̀ pé, “Ní ọ̀la ni Olúwa yóò fi ẹni tí í ṣe tirẹ̀ àti ẹni tó mọ́ hàn, yóò sì mú kí ẹni náà súnmọ́ òun. Ẹni tí ó bá yàn ni yóò mú kí ó súnmọ́ òun.

  2. Ṣùgbọ́n ìpìlẹ̀ Ọlọ́run tí ó dájú dúró ṣinṣin, ó ní èdìdì yìí, pé, “Olúwa mọ àwọn tí í ṣe tirẹ̀.” Àti pẹ̀lú, “Kí olúkúlùkù ẹni tí ń pé orúkọ Olúwa kúrò nínú àìṣòdodo.”