Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: John 2:17, »The zeal of thine house hath eaten me up.«
Àwọn ẹsẹ nípa John 2:17, »The zeal of thine house hath eaten me up.«
nítorí ìtara ilé rẹ jẹ mí run, àti ẹ̀gàn àwọn tí ń gàn ọ́ ṣubú lù mí.
Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì rántí pé, a ti kọ ọ́ pé, “Ìtara ilé rẹ jẹ mí run.”