Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Acts 23:5, »Thou shalt not speak evil of the ruler...«
Àwọn ẹsẹ nípa Acts 23:5, »Thou shalt not speak evil of the ruler...«
“Ìwọ kò gbọdọ̀ sọ̀rọ̀-òdì sí Ọlọ́run tàbí gégùn lé orí ìjòyè àwọn ènìyàn rẹ.
Paulu sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yin arákùnrin mi, èmi kò mọ̀ pé olórí àlùfáà ni: nítorí a tí kọ ọ́ pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ sọ̀rọ̀ olórí àwọn ènìyàn rẹ̀ ní búburú.’ ”