Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Luke 1:17, »...to turn the hearts of the fathers...«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Luke 1:17, »...to turn the hearts of the fathers...«

  1. Òun yóò sì pa ọkàn àwọn baba dà sí ti àwọn ọmọ, àti ọkàn àwọn ọmọ sì ti àwọn baba wọn, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, èmi yóò wá, èmi yóò sì fi ilẹ̀ náà gégùn.”

  2. Ẹ̀mí àti agbára Elijah ni Olúwa yóò sì fi ṣáájú rẹ̀ lọ, láti pa ọkàn àwọn baba dà sí ti àwọn ọmọ, àti ti àwọn aláìgbọ́ràn sí ọgbọ́n àwọn olóòtítọ́; kí ó le pèsè àwọn ènìyàn tí a múra sílẹ̀ de Olúwa.”