Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Romans 15:9, »...I will confess to thee among the Gentiles...«
Àwọn ẹsẹ nípa Romans 15:9, »...I will confess to thee among the Gentiles...«
Títí láéláé, èmi yóò máa yìn ọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ìwọ Olúwa; èmi yóò sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ.
kí àwọn aláìkọlà kí ó lè yin Ọlọ́run lógo nítorí àánú rẹ̀; gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé: “Nítorí èyí ni èmi ó ṣe yìn ọ́ láàrín àwọn Kèfèrí, Èmi ó sì kọrin sí orúkọ rẹ.”