Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Hebrews 9:20, »This is the blood of the testament...«
Àwọn ẹsẹ nípa Hebrews 9:20, »This is the blood of the testament...«
Nígbà náà ni Mose gbé ẹ̀jẹ̀, ó sì wọn sí àwọn ènìyàn náà lára pé, “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Olúwa ti ṣe pẹ̀lú yín ni ìbámu pẹ̀lú àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.”
Wí pé, “Èyí ní ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Ọlọ́run pàṣẹ fún yín.”