Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: 1 Timothy 5:18, »Thou shalt not muzzle the ox...«
Àwọn ẹsẹ nípa 1 Timothy 5:18, »Thou shalt not muzzle the ox...«
Ìwọ kò gbọdọ̀ di màlúù ti ń tẹ ọkà lẹ́nu.
Nítorí nínú òfin tí Ọlọ́run fún Mose, ni a tí kọ ọ́ pé, “Ìwọ kò gbọdọ̀ di màlúù ti ń tẹ ọkà lẹ́nu.” Ǹjẹ́ màlúù ni Ọlọ́run n ṣe ìtọ́jú rẹ̀ bi?
Nítorí tí Ìwé Mímọ́ wí pé, “Ìwọ kò gbọdọ̀ di màlúù ti ń tẹ ọkà lẹ́nu,” àti pé, “Ọ̀yà alágbàṣe tọ́ sí i.”