Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Matthew 8:17, »Himself took our infirmities...«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Matthew 8:17, »Himself took our infirmities...«

  1. Lóòtítọ́ ó ti ru àìlera wa lọ ó sì ti ru ìbànújẹ́ wa pẹ̀lú, síbẹ̀ a kà á sí ẹni tí Ọlọ́run lù, tí ó lù, tí a sì pọ́n lójú.

  2. Kí èyí tí a ti sọ láti ẹnu wòlíì Isaiah lè ṣẹ pé, “Òun tìkára rẹ̀ gbà àìlera wa, ó sì ń ru ààrùn wa.”