Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Galatians 3:12, »The man that doeth them shall live in them.«
Àwọn ẹsẹ nípa Galatians 3:12, »The man that doeth them shall live in them.«
Ẹ̀yin ó sì máa pa ìlànà mi mọ́ àti òfin mi; Ẹni tí ó ba ṣe, yóò yè nípa wọn. Èmi ni Olúwa.
Òfin kì í sì í ṣe ti ìgbàgbọ́: ṣùgbọ́n, “Ẹni tí ó ba ṣe, yóò yè nípa wọn.”