Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Hebrews 13:6, »The Lord is my helper...«
Àwọn ẹsẹ nípa Hebrews 13:6, »The Lord is my helper...«
Olúwa ń bẹ fún èmi; èmi kì yóò bẹ̀rù. Kí ni ènìyàn lè ṣe sí mi?
Nítorí náà ni àwa ṣe ń fi ìgboyà wí pé, “Olúwa ni olùrànlọ́wọ́ mi, èmi kì yóò bẹ̀rù; kín ni ènìyàn lè ṣe sí mi?”