Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Mark 15:28, »And he was numbered with the transgressors.«

3 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Mark 15:28, »And he was numbered with the transgressors.«

  1. Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńlá òun yóò sì pín ìkógun pẹ̀lú àwọn alágbára, nítorí pé òun jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ fún ikú, tí a sì kà á mọ́ àwọn alárékọjá. Nítorí ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀, ó sì ṣe ìlàjà fún àwọn alárékọjá.

  2. And the scripture was fulfilled, which saith, And he was numbered with the transgressors.

  3. Nítorí mo wí fún yín pé, ‘Èyí tí a ti kọ̀wé rẹ̀ kò lè ṣe kí ó má ṣẹ lára mi, a sì kà á mọ́ àwọn arúfin.’ Nítorí àwọn ohun wọ̀nyí nípa ti èmi yóò ní ìmúṣẹ.” tí a sì kà á mọ́ àwọn alárékọjá.