Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Acts 13:34, »I will give you the sure mercies of David.«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Acts 13:34, »I will give you the sure mercies of David.«

  1. Tẹ́tí sílẹ̀ kí o sì wá sọ́dọ̀ mi; gbọ́ tèmi, kí ọkàn rẹ lè wà láààyè. Èmi yóò dá májẹ̀mú ayérayé pẹ̀lú rẹ, ìfẹ́ òtítọ́ tí mo ṣèlérí fún Dafidi.

  2. Àti ni tí pé Ọlọ́run jí i dìde kúrò nínú òkú, ẹni tí kì yóò tún padà sí ìbàjẹ́ mọ́, ó wí báyìí pé: “ ‘Èmi ó fún yín ní ọ̀rẹ́ mímọ́ Dafidi, tí ó dájú.’