Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Galatians 3:13, »Cursed is every one that hangeth on a tree.«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Galatians 3:13, »Cursed is every one that hangeth on a tree.«

  1. o kò gbọdọ̀ fi òkú rẹ̀ sílẹ̀ sára igi ní gbogbo òru. Gbìyànjú láti sin ín ní ọjọ́ náà gan an, nítorí ẹni tí a bá gbé kọ́ sórí igi wà lábẹ́ ègún Ọlọ́run. Ìwọ kò gbọdọ̀ ba ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fún ọ gẹ́gẹ́ bí ogún jẹ́.

  2. Kristi ti rà wá padà kúrò lọ́wọ́ ègún òfin, ẹni tí a fi ṣe ègún fún wa: nítorí tí a ti kọ ọ́ pé, “Ìfibú ni olúkúlùkù ẹni tí a fi kọ́ sórí igi.”