Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Romans 4:17, »I have made thee a father of many nations.«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Romans 4:17, »I have made thee a father of many nations.«

  1. A kì yóò pe orúkọ rẹ̀ ní Abramu mọ́, bí kò ṣe Abrahamu, nítorí, mo ti sọ ọ́ di baba orílẹ̀-èdè púpọ̀.

  2. Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé, “Mo ti fi ọ́ ṣe baba orílẹ̀-èdè púpọ̀.” Níwájú Ọlọ́run ẹni tí òun gbàgbọ́, ẹni tí ó sọ òkú di ààyè, tí ó sì pè àwọn ohun tí kò sí bí ẹni pé wọ́n wà.