Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Luke 23:30, »...say to the mountains, Fall on us...«

2 ẹsẹ · 252 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Luke 23:30, »...say to the mountains, Fall on us...«

  1. Àwọn ibi gíga tí ẹ tí ń hùwà búburú ni a o parun, èyí ni ẹ̀ṣẹ̀ Israẹli. Ẹ̀gún ọ̀gàn àti ẹ̀gún òṣùṣú yóò hù jáde, yóò sì bo àwọn pẹpẹ wọn. Wọn yóò sọ fún àwọn òkè gíga pé, “Bò wá mọ́lẹ̀!” àti fún àwọn òkè kéékèèké pé, “Ṣubú lù wá!”

  2. Nígbà náà ni “ ‘wọn ó bẹ̀rẹ̀ sí wí fún àwọn òkè kéékèèké pé, “Yí lù wá!” Sí àwọn òkè ńlá, “Bò wá mọ́lẹ̀!” ’