Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Quotations and Allusions: Acts 13:35, »Thou shalt not suffer thine Holy One...«
Àwọn ẹsẹ nípa Acts 13:35, »Thou shalt not suffer thine Holy One...«
nítorí ìwọ kò ní fi ọ̀kan sílẹ̀ nínú isà òkú, tàbí kí ìwọ jẹ́ kí ẹni mímọ́ rẹ kí ó rí ìdíbàjẹ́.
Nítorí ó sì wí nínú Saamu mìíràn pẹ̀lú pé, “ ‘Ìwọ kí yóò jẹ́ kí Ẹni Mímọ́ rẹ rí ìdíbàjẹ́.’