- English
- King James KJV
- Complete Jewish CJB
- World English WEBM
- Berean Standard BSB
- American Standard ASV
- Geneva GNV
- Young's Literal YLT
- Douay-Rheims DRC
- International
- Shqip ALB
- العربية SVD
- বাংলা BN-IRV
- မြန်မာ Judson
- 简体文 CUV-S
- 繁體中文 CUV-T
- Čeština BKR
- Nederlands STVE
- Français LSG
- Deutsch SCH
- Ελληνικά Vamvas
- ગુજરાતી GU-IRV
- Hausa HCB
- עברית Hebrew
- हिन्दी HCV
- Magyar KAROLI
- Bahasa Indonesia INDO-TB
- Italiano Diodati
- 日本語 Kougo
- 한국어 Korean
- മലയാളം MAL
- मराठी MRCV
- Norsk DNB
- فارسی OPV
- Polski BG
- Português Almeida
- Română Cornilescu
- Русский Synodal
- Español RVG
- Kiswahili Neno
- Svenska SV1917
- Tagalog TAG-ADB
- தமிழ் TCV
- తెలుగు TSA
- ภาษาไทย THAI-KJV
- Українська Ohienko
- Tiếng Việt CADMAN
- Yorùbá YCB
circa 1406–1380 BC
Conquest of Canaan
Joshua leads Israel across the Jordan into the promised land, defeating the Canaanite kingdoms one by one.
Àwọn ẹsẹ láti sáà yìí
- Joṣua 19:6nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Beti-Lebaoti àti Ṣarueli, ìlú wọn jẹ́ mẹ́tàlá àti ìletò wọn.
- Joṣua 19:7nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Aini, Rimoni, Eteri àti Aṣani, ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn,
- Joṣua 19:8nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
àti gbogbo àwọn agbègbè ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Beeri (Rama ní gúúsù). Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Simeoni, agbo ilé, ní agbo ilé.
- Joṣua 19:9nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
A mú ogún ìní àwọn ọmọ Simeoni láti ìpín Juda, nítorí ìpín Juda pọ̀ ju èyí tí wọ́n nílò lọ. Báyìí ni àwọn ọmọ Simeoni gba ìní wọn ní àárín ilẹ̀ Juda.
- Joṣua 19:10nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Kèké kẹta jáde fún Sebuluni, ní agbo ilé ní agbo ilé ààlà ìní wọn sì lọ títí dé Saridi.
- Joṣua 19:11nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ó sì lọ sí ìwọ̀-oòrùn ní Marala, ó sì dé Dabbeṣeti, ó sì lọ títí dé odo ní ẹ̀bá Jokneamu.
- Joṣua 19:12nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ó sì yípadà sí ìlà-oòrùn láti Saridi sí ìhà ìlà-oòrùn dé ilẹ̀ Kisiloti-Tabori, ó sì lọ sí Daberati, ó sì gòkè lọ sí Jafia.
- Joṣua 19:13nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Nígbà náà ní o lọ sí ìhà ìlà-oòrùn lọ sí Gati-Heferi àti Eti-Kaṣini, ó sì jáde ní Rimoni, ó sì yí sí ìhà Nea.
- Joṣua 19:14nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ní ibẹ̀, ààlà sì yíká ní ìhà àríwá lọ sí Hnatoni ó sì pín ní àfonífojì Ifita-Eli.
- Joṣua 19:15nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Lára wọn ni Katati, Nahalali, Ṣimroni, Idala àti Bẹtilẹhẹmu. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlá àti ìletò wọn.
- Joṣua 19:16nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní Sebuluni, ní agbo ilé agbo ilé.
- Joṣua 19:17nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Kèké kẹrin jáde fún Isakari, agbo ilé ní agbo ilé.
- Joṣua 19:18nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Lára ilẹ̀ wọn ni èyí: Jesreeli, Kesuloti, Ṣunemu,
- Joṣua 19:19nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Hafraimu, Ṣihoni, Anaharati,
- Joṣua 19:20nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Rabiti, Kiṣioni, Ebesi,
- Joṣua 19:21nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Remeti, Eni-Gannimu, Eni-Hada àti Beti-Pasesi.
- Joṣua 19:22nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ààlà náà sì dé Tabori, Ṣahasuma, àti Beti-Ṣemeṣi, ó sì pin ní Jordani. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún àti ìletò wọn.
- Joṣua 19:23nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní ẹ̀yà Isakari, ní agbo ilé agbo ilé.
- Joṣua 19:24nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Kèké karùn-ún jáde fún ẹ̀yà Aṣeri, ní agbo ilé agbo ilé.
- Joṣua 19:25nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Lára ilẹ̀ wọn ni èyí: Helikati, Hali, Beteni, Akṣafu,
- Joṣua 19:26nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Allameleki, Amadi, àti Miṣali. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ààlà náà dé Karmeli àti Ṣihori-Libinati.
- Joṣua 19:27nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Nígbà náà ni o yí sí ìhà ìlà-oòrùn Beti-Dagoni, dé Sebuluni àti àfonífojì Ifita-Eli, ó sì lọ sí àríwá sí Beti-Emeki àti Neieli, ó sì kọjá lọ sí Kabulu ní apá òsì.
- Joṣua 19:28nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ó sì lọ sí Abdoni, Rehobu, Hammoni àti Kana títí dé Sidoni ńlá.
- Joṣua 19:29nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ààlà náà sì tẹ̀ sí ìhà Rama, ó sì lọ sí ìlú olódi Tire, ó sì yà sí Hosa, ó sì jáde ní Òkun Ńlá ní ilẹ̀ Aksibu,
- Joṣua 19:30nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Uma, Afeki àti Rehobu. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlélógún àti ìletò wọn.