- English
- King James KJV
- Complete Jewish CJB
- World English WEBM
- Berean Standard BSB
- American Standard ASV
- Geneva GNV
- Young's Literal YLT
- Douay-Rheims DRC
- International
- Shqip ALB
- العربية SVD
- বাংলা BN-IRV
- မြန်မာ Judson
- 简体文 CUV-S
- 繁體中文 CUV-T
- Čeština BKR
- Nederlands STVE
- Français LSG
- Deutsch SCH
- Ελληνικά Vamvas
- ગુજરાતી GU-IRV
- Hausa HCB
- עברית Hebrew
- हिन्दी HCV
- Magyar KAROLI
- Bahasa Indonesia INDO-TB
- Italiano Diodati
- 日本語 Kougo
- 한국어 Korean
- മലയാളം MAL
- मराठी MRCV
- Norsk DNB
- فارسی OPV
- Polski BG
- Português Almeida
- Română Cornilescu
- Русский Synodal
- Español RVG
- Kiswahili Neno
- Svenska SV1917
- Tagalog TAG-ADB
- தமிழ் TCV
- తెలుగు TSA
- ภาษาไทย THAI-KJV
- Українська Ohienko
- Tiếng Việt CADMAN
- Yorùbá YCB
circa 1406–1380 BC
Conquest of Canaan
Joshua leads Israel across the Jordan into the promised land, defeating the Canaanite kingdoms one by one.
Àwọn ẹsẹ láti sáà yìí
- Joṣua 15:50nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Anabu, Eṣitemo, Animu,
- Joṣua 15:51nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Goṣeni, Holoni àti Giloni, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.
- Joṣua 15:52nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Arabu, Duma, Eṣani,
- Joṣua 15:53nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Janimu, Beti-Tapua, Afeka,
- Joṣua 15:54nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Hamuta, Kiriati-Arba (tí í ṣe, Hebroni) àti Ṣiori: ìlú mẹ́sàn-án àti àwọn ìletò rẹ̀
- Joṣua 15:55nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Maoni, Karmeli, Sifi, Jutta,
- Joṣua 15:56nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Jesreeli, Jokdeamu, Sanoa,
- Joṣua 15:57nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Kaini, Gibeah àti Timna: ìlú mẹ́wàá àti àwọn ìletò wọn.
- Joṣua 15:58nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Halhuli, Beti-Suri, Gedori,
- Joṣua 15:59nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Maarati, Beti-Anoti àti Eltekoni: ìlú mẹ́fà àti àwọn ìletò wọn.
- Joṣua 15:60nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Kiriati-Baali (tí í ṣe, Kiriati-Jearimu) àti Rabba ìlú méjì àti ìletò wọn.
- Joṣua 15:61nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ní aginjù: Beti-Araba, Middini, Sekaka,
- Joṣua 15:62nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Nibṣani, Ìlú Iyọ̀ àti En-Gedi: ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn.
- Joṣua 15:63nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Juda kò lè lé àwọn ọmọ Jebusi jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jerusalẹmu. Àwọn ará Jebusi sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Juda títí dí òní.
- Joṣua 16:1nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ìpín ti àwọn ọmọ Josẹfu láti Jordani lẹ́bàá Jeriko, ní omi Jeriko ní ìhà ìlà-oòrùn, àní aginjù, tí ó gòkè láti Jeriko lọ dé ilẹ̀ òkè Beteli.
- Joṣua 16:2nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ó sì tẹ̀síwájú láti Beteli (tí í ṣe Lusi) kọjá lọ sí agbègbè àwọn ará Arki ní Atarotu,
- Joṣua 16:3nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn agbègbè àwọn ará Jefileti, títí dé ilẹ̀ ìsàlẹ̀ Beti-Horoni, àní dé Geseri, ó sì parí sí etí Òkun.
- Joṣua 16:4nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Báyìí ni Manase àti Efraimu, àwọn ọmọ Josẹfu, gba ilẹ̀ ìní wọn.
- Joṣua 16:5nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Èyí ni ilẹ̀ Efraimu, ní agbo ilé agbo ilé. Ààlà ìní wọn lọ láti Atarotu-Addari ní ìlà-oòrùn lọ sí òkè Beti-Horoni.
- Joṣua 16:6nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ó sì lọ títí dé Òkun. Láti Mikmeta ní ìhà àríwá, ó sì yí lọ sí ìhà ìlà-oòrùn lọ sí Taanati-Ṣilo, ó sì kọjá ní ẹ̀bá rẹ̀ lọ sí Janoa ní ìlà-oòrùn.
- Joṣua 16:7nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Láti Janoa ó yípo lọ sí gúúsù sí Atarotu àti Naara, ó sì dé Jeriko, ó sì pín sí odò Jordani.
- Joṣua 16:8nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Láti Tapua ààlà náà sì lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn, ní Kana-Rafini, ó sì parí ní Òkun. Èyí ni ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Efraimu, ní agbo ilé agbo ilé.
- Joṣua 16:9nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ó tún mú àwọn ìlú àti ìletò wọn tí ó yà sọ́tọ̀ fún àwọn ọmọ Efraimu tí ó wà ní àárín ìní àwọn ọmọ Manase.
- Joṣua 16:10nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Wọn kò lé àwọn ara Kenaani tí ń gbé ni Geseri kúrò, títí di òní yìí ni àwọn ará Kenaani ń gbé láàrín àwọn ènìyàn Efraimu, ṣùgbọ́n wọ́n mú wọ́n sìn.
- Joṣua 17:1nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Èyí ní ìpín ẹ̀yà Manase tí í ṣe àkọ́bí Josẹfu, fún Makiri, àkọ́bí Manase. Makiri sì ni baba ńlá àwọn ọmọ Gileadi, tí ó ti gba Gileadi àti Baṣani nítorí pé àwọn ọmọ Makiri jẹ́ jagunjagun ńlá.