- English
- King James KJV
- Complete Jewish CJB
- World English WEBM
- Berean Standard BSB
- American Standard ASV
- Geneva GNV
- Young's Literal YLT
- Douay-Rheims DRC
- International
- Shqip ALB
- العربية SVD
- বাংলা BN-IRV
- မြန်မာ Judson
- 简体文 CUV-S
- 繁體中文 CUV-T
- Čeština BKR
- Nederlands STVE
- Français LSG
- Deutsch SCH
- Ελληνικά Vamvas
- ગુજરાતી GU-IRV
- Hausa HCB
- עברית Hebrew
- हिन्दी HCV
- Magyar KAROLI
- Bahasa Indonesia INDO-TB
- Italiano Diodati
- 日本語 Kougo
- 한국어 Korean
- മലയാളം MAL
- मराठी MRCV
- Norsk DNB
- فارسی OPV
- Polski BG
- Português Almeida
- Română Cornilescu
- Русский Synodal
- Español RVG
- Kiswahili Neno
- Svenska SV1917
- Tagalog TAG-ADB
- தமிழ் TCV
- తెలుగు TSA
- ภาษาไทย THAI-KJV
- Українська Ohienko
- Tiếng Việt CADMAN
- Yorùbá YCB
circa 1406–1380 BC
Conquest of Canaan
Joshua leads Israel across the Jordan into the promised land, defeating the Canaanite kingdoms one by one.
Àwọn ẹsẹ láti sáà yìí
- Joṣua 15:25nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Hasori Hadatta, Kerioti Hesroni (tí í ṣe Hasori),
- Joṣua 15:26nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Amamu, Ṣema, Molada,
- Joṣua 15:27nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Hasari Gada, Heṣmoni, Beti-Peleti,
- Joṣua 15:28nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Hasari-Ṣuali, Beerṣeba, Bisiotia,
- Joṣua 15:29nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Baalahi, Limu, Esemu,
- Joṣua 15:30nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Eltoladi, Kesili, Horma,
- Joṣua 15:31nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Siklagi, Madmana, Sansanna,
- Joṣua 15:32nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Leboati, Ṣilhimu, Aini àti Rimoni, àpapọ̀ ìlú mọ́kàndínlọ́gbọ̀n àti àwọn ìletò wọn.
- Joṣua 15:33nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ẹsẹ̀ òkè: Eṣtaoli, Sora, Aṣna,
- Joṣua 15:34nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Sanoa, Eni-Gannimu, Tapua, Enamu,
- Joṣua 15:35nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Jarmatu, Adullamu, Soko, Aseka,
- Joṣua 15:36nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ṣaaraimu, Adittaimu àti Gedera (tàbí Gederotaimu). Ìlú mẹ́rìnlá àti àwọn ìletò wọn.
- Joṣua 15:37nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Senani, Hadaṣa, Migdali Gadi,
- Joṣua 15:38nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Dileani, Mispa, Jokteeli,
- Joṣua 15:39nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Lakiṣi, Boskati, Egloni,
- Joṣua 15:40nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Kabboni, Lamasi, Kitlisi,
- Joṣua 15:41nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Gederoti, Beti-Dagoni, Naama àti Makkeda, ìlú mẹ́rìndínlógún àti ìletò wọn.
- Joṣua 15:42nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Libina, Eteri, Aṣani,
- Joṣua 15:43nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Hifita, Aṣna, Nesibu,
- Joṣua 15:44nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Keila, Aksibu àti Meraṣa: ìlú mẹ́sàn-án àti àwọn ìletò wọn.
- Joṣua 15:45nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ekroni, pẹ̀lú ibùgbé àti àwọn ìletò rẹ̀ tó yí i ká,
- Joṣua 15:46nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
ìwọ̀-oòrùn Ekroni, gbogbo èyí tí ń bẹ nítòsí Aṣdodu, pẹ̀lú àwọn ìletò wọn,
- Joṣua 15:47nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Aṣdodu, agbègbè ìlú rẹ̀ àti ìletò; àti Gasa, ìlú rẹ̀ àti ìletò, títí ó fi dé odò Ejibiti àti agbègbè Òkun Ńlá.
- Joṣua 15:48nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Ní ilẹ̀ òkè náà: Ṣamiri, Jattiri, Soko,
- Joṣua 15:49nǹkan bí 1443 ṣáájú Kristi
Dannah, Kiriati-Sannnah (tí í ṣe Debiri),