- English
- King James KJV
- Complete Jewish CJB
- World English WEBM
- Berean Standard BSB
- American Standard ASV
- Geneva GNV
- Young's Literal YLT
- Douay-Rheims DRC
- International
- Shqip ALB
- العربية SVD
- বাংলা BN-IRV
- မြန်မာ Judson
- 简体文 CUV-S
- 繁體中文 CUV-T
- Čeština BKR
- Nederlands STVE
- Français LSG
- Deutsch SCH
- Ελληνικά Vamvas
- ગુજરાતી GU-IRV
- Hausa HCB
- עברית Hebrew
- हिन्दी HCV
- Magyar KAROLI
- Bahasa Indonesia INDO-TB
- Italiano Diodati
- 日本語 Kougo
- 한국어 Korean
- മലയാളം MAL
- मराठी MRCV
- Norsk DNB
- فارسی OPV
- Polski BG
- Português Almeida
- Română Cornilescu
- Русский Synodal
- Español RVG
- Kiswahili Neno
- Svenska SV1917
- Tagalog TAG-ADB
- தமிழ் TCV
- తెలుగు TSA
- ภาษาไทย THAI-KJV
- Українська Ohienko
- Tiếng Việt CADMAN
- Yorùbá YCB
Creation Era
The Tower of Babel
Scattered nations and confused languages mark the beginning of the diversity of peoples across the earth.
Àwọn ẹsẹ láti sáà yìí
Èyí ni ìran àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi.
Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi.
Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.
- Gẹnẹsisi 10:4nǹkan bí 2338 ṣáájú Kristi
Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu.
- Gẹnẹsisi 10:5nǹkan bí 2247 ṣáájú Kristi
(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀).
- Gẹnẹsisi 10:6nǹkan bí 2228 ṣáájú Kristi
Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani.
- Gẹnẹsisi 10:7nǹkan bí 2228 ṣáájú Kristi
Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka. Àwọn ọmọ Raama ni: Ṣeba àti Dedani.
- Gẹnẹsisi 10:8nǹkan bí 2289 ṣáájú Kristi
Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.
- Gẹnẹsisi 10:9nǹkan bí 2289 ṣáájú Kristi
Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.”
- Gẹnẹsisi 10:10nǹkan bí 2259 ṣáájú Kristi
Ìjọba rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni Babeli, Ereki, Akkadi, Kalne, gbogbo wọn wà ní ilẹ̀ Ṣinari.
- Gẹnẹsisi 10:11nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Láti ilẹ̀ náà ni ó ti lọ sí Asiria, níbi tí ó ti tẹ ìlú Ninefe, Rehoboti àti Kala,
- Gẹnẹsisi 10:12nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
àti Resini, tí ó wà ní àárín Ninefe àti Kala, tí ó jẹ́ ìlú olókìkí.
- Gẹnẹsisi 10:13nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Ejibiti sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu.
- Gẹnẹsisi 10:14nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.
- Gẹnẹsisi 10:15nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀, àti Heti.
- Gẹnẹsisi 10:16nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi,
- Gẹnẹsisi 10:17nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini,
- Gẹnẹsisi 10:18nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati. Lẹ́yìn èyí ni àwọn ẹ̀yà Kenaani tànkálẹ̀.
- Gẹnẹsisi 10:19nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Ààlà ilẹ̀ àwọn ará Kenaani sì dé Sidoni, lọ sí Gerari títí dé Gasa, lọ sí Sodomu, Gomorra, Adma àti Seboimu, títí dé Laṣa.
- Gẹnẹsisi 10:20nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Hamu, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, àti èdè wọn, ní ìpínlẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn.
- Gẹnẹsisi 10:21nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
A bí àwọn ọmọ fún Ṣemu tí Jafeti jẹ́ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin: Ṣemu sì ni baba gbogbo àwọn ọmọ Eberi.
- Gẹnẹsisi 10:22nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu.
- Gẹnẹsisi 10:23nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Àwọn ọmọ Aramu ni: Usi, Huli, Geteri àti Meṣeki.
- Gẹnẹsisi 10:24nǹkan bí 2304 ṣáájú Kristi
Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.
- Gẹnẹsisi 10:25nǹkan bí 2247 ṣáájú Kristi
Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.