Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Naphtali: Bounds of their inheritance

8 ẹsẹ · 26 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Bounds of their inheritance

  1. Ìpín kẹfà jáde fún Naftali, agbo ilé ní agbo ilé,

  2. ààlà wọn lọ láti Helefi àti igi ńlá ní Saananimu nímù; kọjá lọ sí Adami Nekebu àti Jabneeli dé Lakkumu, ó sì pín ní Jordani.

  3. Ààlà náà gba ìhà ìwọ̀-oòrùn lọ sí Asnoti-Tabori ó sì jáde ní Hukoki. Ó sì dé Sebuluni, ní ìhà gúúsù Aṣeri ní ìhà ìwọ̀-oòrùn àti Juda ní Jordani ní ìhà ìlà-oòrùn.

  4. Àwọn ìlú olódi sì Siddimu, Seri, Hamati, Rakàti, Kinnereti,

  5. Adama, Rama Hasori,

  6. Kedeṣi, Edrei, Eni-Aṣọri,

  7. Ironi, Migdali-Eli, Horemu, Beti-Anati àti Beti-Ṣemeṣi. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mọ́kàndínlógún àti ìletò wọn.

  8. Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Naftali, ní agbo ilé sí agbo ilé.