Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Naphtali: Land of, ravaged by Benhadad
Àwọn ẹsẹ nípa Land of, ravaged by Benhadad
Beni-Hadadi gba ti Asa ọba, ó sì rán àwọn alágbára olórí ogun rẹ̀ sí àwọn ìlú Israẹli. Ó sì ṣẹ́gun Ijoni, Dani àti Abeli-Beti-Maaka, àti gbogbo Kinnereti pẹ̀lú gbogbo ilẹ̀ Naftali.