Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Naphtali: The rear of the fourth division of Israel in their journeys

2 ẹsẹ · 26 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The rear of the fourth division of Israel in their journeys

  1. Lákòótan, àwọn ọmọ-ogun tó ń mójútó ẹ̀yìn ló tún kàn, àwọn ni ìpín ti ibùdó Dani lábẹ́ ọ̀págun wọn. Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai ni ọ̀gágun wọn.

  2. Ahira ọmọ Enani ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Naftali.