Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Naphtali: Taken captive by Tiglathpileser
Àwọn ẹsẹ nípa Taken captive by Tiglathpileser
Ní ìgbà Peka ọba Israẹli, Tiglat-Pileseri ọba Asiria wá, ó sì mú Ijoni, Abeli-Beti-Maaka, Janoa, Kedeṣi àti Hasori. Ó gba Gileadi àti Galili pẹ̀lú gbogbo ilẹ̀ Naftali. Ó sì kó àwọn ènìyàn ní ìgbèkùn lọ sí Asiria.