Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Naphtali: Encamped under the standard of Dan north of the tabernacle

2 ẹsẹ · 26 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Encamped under the standard of Dan north of the tabernacle

  1. Ní ìhà àríwá: ni ìpín Dani yóò pa ibùdó sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olórí Dani ni Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai.

  2. Ẹ̀yà Naftali ni yóò kàn lẹ́yìn wọn. Olórí Naftali ni Ahira ọmọ Enani.