Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Naphtali: Descended from Jacob's sixth son
Àwọn ẹsẹ nípa Descended from Jacob's sixth son
Biliha, ọmọ ọ̀dọ̀ Rakeli sì tún lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kejì fún Jakọbu.
Nígbà náà ni Rakeli wí pé, “Mo ti bá ẹ̀gbọ́n mi ja ìjàkadì ńlá, èmi sì ti borí.” Ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Naftali.