Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Naphtali: Joined Gideon in the pursuit and overthrow of the Midianites
Àwọn ẹsẹ nípa Joined Gideon in the pursuit and overthrow of the Midianites
Gbogbo àwọn ọmọ-ogun Israẹli láti ẹ̀yà Naftali, Aṣeri àti gbogbo Manase ni Gideoni ránṣẹ́ si, wọ́n wá wọ́n sì lé àwọn ará Midiani.