Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Refers the question as to circumcision to the apostles and elders at Jerusalem

2 ẹsẹ · 103 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Refers the question as to circumcision to the apostles and elders at Jerusalem

  1. Nígbà tí Paulu àti Barnaba ni ìyapa àti ìyàn jíjà tí kò mọ níwọ̀n pẹ̀lú ara wọn, wọ́n yan Paulu àti Barnaba àti àwọn mìíràn nínú aposteli kí wọn gòkè lọ sí Jerusalẹmu, sọ́dọ̀ àwọn alàgbà nítorí ọ̀ràn yìí.

  2. Nígbà tí wọn sì dé Jerusalẹmu, ìjọ àti àwọn aposteli àti àwọn alàgbà tẹ́wọ́gbà wọ́n, wọ́n sì ròyìn ohun gbogbo tí Ọlọ́run ti ṣe nípasẹ̀ wọn.