Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Persecuted by the Jews who come from Thessalonica; is conducted by the brethren to Athens

3 ẹsẹ · 103 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Persecuted by the Jews who come from Thessalonica; is conducted by the brethren to Athens

  1. Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn Júù tí Tẹsalonika mọ̀ pé, Paulu ń wàásù ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní Berea, wọ́n wá síbẹ̀ pẹ̀lú, wọ́n rú àwọn ènìyàn sókè.

  2. Nígbà náà ni àwọn arákùnrin rán Paulu jáde lọ́gán láti lọ títí de etí Òkun, ṣùgbọ́n Sila àti Timotiu dúró ní Berea.

  3. Àwọn tí ó sin Paulu wá sì mú un lọ títí dé Ateni; nígbà tí wọ́n sì gba àṣẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ wá fún Sila àti Timotiu pé, ki wọn ó yára tọ òun wá, wọ́n lọ.