Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Transferred to a ship of Alexandria; sails by way of Cnidus, Crete, Salamis, and the Fair Havens

3 ẹsẹ · 103 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Transferred to a ship of Alexandria; sails by way of Cnidus, Crete, Salamis, and the Fair Havens

  1. Níbẹ̀ ni balógun ọ̀rún sì rí ọkọ̀-òkun Alekisandiria kan, ti ń lọ sí Itali; ó sì fi wa sínú rẹ̀.

  2. Nígbà tí a ń lọ jẹ́jẹ́ ní ọjọ́ púpọ̀, ti a fi agbára káká dé ọ̀kánkán Knidu, àti nítorí tí afẹ́fẹ́ kò fún wa láààyè, a ba ẹ̀bá Krete lọ, lọ́kankán Salmoni.

  3. Nígbà tí a sì fi agbára káká kọjá rẹ̀, a dé ibi tí a ń pè ní Èbùté Yíyanjú, tí ó súnmọ́ ìlú Lasea.