Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Preaches at Salamis
Àwọn ẹsẹ nípa Preaches at Salamis
Nígbà ti wọ́n sì wà ni Salami, wọ́n ń wàásù ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní Sinagọgu àwọn Júù. Johanu náà sì wà pẹ̀lú wọn láti ràn wọ́n lọ́wọ́ fún ìránṣẹ́ wọn.