Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Goes through Phrygia and Galatia; is forbidden by the Holy Ghost to preach in Asia; visits Mysia; essays to go to Bithynia, but is restrained by the Spirit; goes to Troas, where he has a vision of a man saying, »Come over into Macedonia, and help us;« imm

5 ẹsẹ · 103 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Goes through Phrygia and Galatia; is forbidden by the Holy Ghost to preach in Asia; visits Mysia; essays to go to Bithynia, but is restrained by the Spirit; goes to Troas, where he has a vision of a man saying, »Come over into Macedonia, and help us;« imm

  1. Wọ́n sì la agbègbè Frigia já, àti Galatia, nítorí tí Ẹ̀mí Mímọ́ kọ̀ fún wọn láti sọ ọ̀rọ̀ náà ni Asia.

  2. Nígbà tí wọ́n dé ọ̀kánkán Misia, wọ́n gbìyànjú láti lọ sí Bitinia, ṣùgbọ́n Ẹ̀mí Jesu kò gbà fún wọn.

  3. Nígbà tí wọ́n sì kọjá lẹ́bàá Misia, wọ́n sọ̀kalẹ̀ lọ sí Troasi.

  4. Ìran kan si hàn sì Paulu ni òru, ọkùnrin kan ará Makedonia dúró, ó sì ń bẹ̀ ẹ́, wí pé, “Rékọjá wá sí Makedonia, kí o sí ràn wá lọ́wọ́!”

  5. Nígbà tí ó sì tí rí ìran náà, lọ́gán ó múra láti lọ sí Makedonia, a ka á sí pé, Ọlọ́run tí pè wá láti wàásù ìyìnrere fún wọn.