Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Makes his second tour of the churches
Àwọn ẹsẹ nípa Makes his second tour of the churches
Lẹ́yìn ọjọ́ mélòó kan, Paulu sì sọ fún Barnaba pé, “Jẹ́ kí a tún padà lọ bẹ àwọn arákùnrin wa wò, bí wọn ti ń ṣe sí ni ìlú gbogbo tí àwa ti wàásù ọ̀rọ̀ Olúwa.”