Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paul: Is confined in Herod's Judgment Hall in Caesarea
Àwọn ẹsẹ nípa Is confined in Herod's Judgment Hall in Caesarea
Ó wí pé, “Èmi yóò gbọ́ ẹjọ́ rẹ, nígbà tí àwọn olùfisùn rẹ pẹ̀lú bá dé.” Ó sì pàṣẹ pé kí wọn pa Paulu mọ́ ní abẹ́ àbojútó àwọn olùṣọ́ ní gbọ̀ngàn ìdájọ́ ààfin Herodu.